Awon Onidajo 14-16

Ki eniyan le se aseyori lai se ase yo’wo yio fi wa jo Jesu Oluwa wa.

Awon Onidajo 12-13

Eni to ba fi ti Oloryn se yio bori ogun ko’gun ti o ba too wa

Awon Onidajo 11:11-40

Bi a ba se ileri se ileri fun Olorun ati eniyan oye ki a se pelu idari Emimo.

Awon Onidajo 10:3-11:10

Ogun kii dede bere bi ko ba si eni ti Esu yio lo.

Awon Onidajo 8:1-10:2

Olorun dariji enikeni ti oba se tan lati kuro ni ese re.

Awon Onidajo 6:36-7:25

Osi, aina ati iku ojiji ni n se isokun fa lati ilu ese wa

Awon Onidajo 6:1-35

Olorun lo Gideoni lati gba awon omo Isreli

Awon Onidajo 5

Awon Onidajo 3:12-4:24

Osi, aina ati iku ojiji ni n se isokun fa lati ilu ese wa.

Awon Onidajo 1:1-3:11

Olorun fun rara re lon se ijoba ni ile isreli

Josua 23-24

Josua so wipe ki won mura gidigidi lati toju ati lati se ohun gbogbo ti o wa ninu ofin Mose