Gbo
Ìgbẹ́kẹ̀lé Ẹni Tí Ó Dàbí Ilé Aláǹtakùn

Ìwé Jobù fi àpẹẹrẹ tó dára hàn fún wa nípa ẹni tí ó gbàgbé Ọlọ́run nínú ayé rẹ̀. Ẹ gbọ́: “Bẹ́ẹ̀ ni ipa ọ̀nà gbogbo àwọn tí ó gbàgbé Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni ìrètí àwọn àgàbàgebè yóò di òfo. Àbá ẹni tí a ó kèé kúrò, àti ìgbẹ́kẹ̀lé ẹni tí ó dàbí ilé aláǹtakùn.