Gbo
Bẹrẹ Sí Ní Mọ̀ Ọkàn Rẹ

Ọkan lára àwọn ìdí tí ìwé Orin Dafidi nínú Bíbélì fi fà wá mọ́ra ni pé àwọn ìwé náà kan àwọn ìrírí tó wọ́pọ̀ fún gbogbo wa. Nínú Orin Dafidi ni a ti máa ń rí gbogbo ìmọ̀lára ènìyàn: ìdúpẹ́, ìbínú, ìfẹ́, ìkórìíra, ayọ̀, àti bebe lo.