Ṣùgbọ́n Louise jẹ́ onígbàgbọ́ ninu Jésù Kristi láti ìkókó. Àpẹẹrẹ Ẹ̀mí Ọlọ́run nínú ìgbésí ayé rẹ̀ ni pé ó fi ìfẹ́, ìgbàgbọ́, àlàáfíà, ìbáṣepọ̀, ìgboyà àti ẹ̀mí ìṣẹ́gun hàn gẹ́gẹ́ bí àpẹẹrẹ tí mo kà. Kò fi púpọ̀ sí ìbéèrè bí “Kí nìdí tó fi ń ṣẹlẹ̀ sí mi?”