Gbo
Sọ Fún Wọn Gbogbo Ohun Tí Ọlọrun Ti Ṣe Fún Rẹ

Ó dájú pé bí ẹbí rẹ̀ bá rí i, wọ́n á mọ̀ pé ó ti yí padà. Ṣùgbọ́n ìtàn iwòsàn rẹ̀ lè jẹ́ ohun tó dun gidigidi láti gbọ́! Rò ó, bóyá ní alẹ́ náà níbi onjẹ, gbogbo ìtàn tí yóò sọ nípa ìgbà tí Jesu mú lára dáa. Ìwọ nko? Ṣé ìwọ ti sọ fún ẹbí rẹ nípa àwọn ohun pàtàkì tí Ọlọrun ṣe fún ọ laipẹ?