Gbo
Ohun Mẹrin Lati Ma Ranti Nigba Ti O Ba Dojuko Nkan Kan Ti O Tobi Ju Ẹ̀ Lọ

Nigbati Ọlọrun n sọ fún Mose, O mọ̀ pé àwọn ènìyàn Rẹ yóò padà ba ọ̀tá tí ó lagbara ju wọn lọ. Nítorí náà, Ọlọrun sọ fún Mose pé: “Nígbà tí o bá lọ sí ogun pẹ̀lú ọ̀tá rẹ, tí o sì rí ẹṣin àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun àti ológun tí ó jù ọ́ lọ, má ṣe bẹ̀rù u wọn, nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ tí ń mú ọ jáde wá láti ilẹ̀ Ejibiti, yóò wà pẹ̀lú rẹ. Nígbà tí o bá fẹ́ lọ jagun, àlùfáà yóò wá síwájú, yóò sì bá ọmọ-ogun sọ̀rọ̀, yóò sì wí pé, “Gbọ́, ìwọ Israẹli, lónìí ò ń jáde lọ sójú ogun sí ọ̀tá rẹ.