Gbo
Kí ni Ọkàn ní Ṣe Pẹ̀lú Fífúni?

ṣẹ́ ìránṣẹ́ yìí ni a ń pè ní “Jakẹ́ẹ̀tì fún Jesu” (Jackets for Jesus), iṣẹ́ tó wúlò gan-an ni. Ní gbogbo ìrọ̀lẹ́ Ọjọ́ Àìkú, Pastor Eric Denton máa gba ẹgbẹ́ kan ti àwọn ènìyàn kọjá aadọta maili láti Riverside California lọ sí àwọn opopona Los Angeles láti fún àwọn ènìyàn ọ̀nà ní oúnjẹ tó gbóná àti láti fi ìfẹ́ Jesu hàn fún wọn— Àwọn ènìyàn tí ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé èyí nikan ni ẹ̀bùn ìfẹ́ tí wọ́n máa rí. Bẹ́ẹ̀ ni, tí wọ́n bá tutù, wọ́n á tún gba jakẹ́ẹ̀tì tó dára tí ẹlòmíràn ti lo rí.