Gbo
Dúró Kí O Sì Wo Ènìyàn Gẹ́gẹ́ Bí Wọ́n Ṣe Jẹ́ Gangan

Ó ṣẹlẹ̀ ní gúúsù India ní ọdún 1940s. Ọmọkùnrin abúlé kan tó jẹ́ ọmọ ọdún méjìlá ń ràn Dókítà Margaret Brand, dókítà ìránṣẹ́ tí ń ṣe iṣẹ́ abẹ̀ ojú, lọ́wọ́. Gẹ́gẹ́ bí ó ti rí, ọ̀kan lára àwọn aláìsàn náà ni . . .