Gbo
Kí Ni Ìtúmọ̀ Rẹ̀ Gangan Pé “Nílé Pẹ̀lú Olúwa”?

Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ pé gbogbo ènìyàn fẹ́ lọ sí ọ̀run lẹ́yìn ikú. Ó dájú pé kò sí ẹni tó fẹ́ lọ sí ọ̀run apadi! Ṣùgbọ́n ṣé o ti ronú pé báwo ni yóò ṣe rí bí o bá jí ní òwúrọ̀ kan, o sì rí ara rẹ̀ ní ọ̀run—ṣùgbọ́n ìwọ kò mọ̀ ibi kankan tàbí bí wọ́n ṣe ń ṣe níbẹ̀?