Kí ló dé tí díẹ̀ nínú àwọn ènìyàn fi máa ń tọ́jú ẹlòmíì, ṣùgbọ́n àwọn mìíràn sì ń ṣàkíyèsí ara wọn nìkan? Ṣé ó ṣeé ṣe kí ẹni tó jẹ́ aláìnífẹ̀ẹ́ di ẹni tó ń tọ́jú ẹlòmíì? Ìwé Mímọ́ sọ nípa ọ̀pọ̀ ènìyàn tí ìgbésí ayé wọn yí padà lẹ́yìn tí wọ́n pàdé Jésù.