Gbo
IRAPADA WÀ NÍNÚ ÀWỌN IPARUN

Ronu nípa àwọn iparun ńlá ayé—bí Pírámídì ilẹ̀ Ejibiti tàbí Stonehenge ní ilẹ̀ England. Nígbà tá a bá rí ahoro tabi iparun, jẹ ki a duro pelu iyalẹnu pe, “Kí ló ṣẹlẹ̀ níbí?”