Gbo
Josua 4:19-5:15

Awon okuta ti Josua to won yi ni ofi se ami lati se iranti ati lati je ki awon omo lehin ola mo pe won la jodani koja ni ile gbigbe