Jobu 9-10
-
Jobu 9
Close
Jobu 6:16--8:22
Ko ye ki alaigbagbo ma fi Olorun wa bu ki a ma fun won ni esi ti ogbon Orun wa
Jobu 5:7-6:15
bi awon elese ban tayo ni awujo wa, wu kii se awokose fun onigbagbo
Jobu 4:1-5:7
owo epo ni omo araye n bani la ,Jobu ti o n gba awon enyan ni iyanju ti ko si le gba ara re ni yanju ni Elifasi wi.
Jobu 3:14-26
Olorun ti mo odi aabo yi gbogbo eniyan ka, onigbagbo tabi alai gbagbo.
Jobu 2:4-3:13
Ni ojo kan emi ati iwo na yio wa si iwaju Olorun lati jabo ise wa fun, nitori ohun ni eleda wa.
Jobu 1:6-2:3
ile aye yi je ibi joko Satani, ko ti'n lo si orun apaadi.
Jobu 1:1-5
ile Usi je ile ti Jobu ngbe
Esteri 9-10
Nigbati ireti ba pin Olorun a dide iranlowo
Esteri 8
asiko ti Olorun ba fe eniyan tiko ba se, yio ri ifarahan ogo re
Esteri 6:7-7:10
eni ti yio se aanu fun kole sa lai se