Galatia 6:11-18

Ayo kan soso ti ani gege bi omo lehin Jesu ni Ayo Igbala, Idunu wa le wa lorin awon ohun ini wa.

Galatia 6:6-11

Ise iranse Paulu funrare pelu ihinrere si awon Kenferi nitori Jesu ko wa fun awon ju nikan.

Galatia 6:1-5

Eniyan ti o ba ti fi gbogbo aye re fun Olorun na ni ao mo nipa eso Emi ti o je jade ninu aye re.

Galatia 5:22-26

eje ki a kiyesi awon arekekre Esu ninu ijo wa ati igbe aye wa gege bi onigbagbo

Galatia 5: 16-21

Irin ajo Emi ko see se pelu eran ara

Galatia 5:5-16

Ise ofin ninu aye onigbagbo ko ipa to o po sibi isubu

Galatia 5:1-4

Emi ni 'n so wa ni aaye

Galatia 4:9-31

Abrhamu ni lati yan laarin omo Hagai ati omo Sara

Galatia 4:6-24

iye awon ti o gba Olorun gbo ni o ni amfanilati di omoo Olorun

Galatia 4:1-7

Niwon ti a ko le gba imoran fun ara wa , a je ope ninu Kristi

Galatia 3:19-29

Ofin kii se agbara wa sugbon oreofe ninu Kristi Jesu