Romu 10:7-11:10

Kristi ni opin gbogbo ofin

Romu 9:25-10:10

Ipo Isreali ni wipe won sonu, eyi si ni ipo won loni

Romu 9:4-24

Aposteli Paulu se alaye kikun lori awon ti ayan ati awon ti akoyan

Romu 9:1-4

Awon omo Isreali ni awon ti a rapada,ti ni ogo, awon oni majemu

Romu 8:28-39

Ohun gbogbo nsise po fun rere fun omo igbala

Romu 8:18-28

Orun ki koko ati ireti onigbagbo

Romu 8:9-17

Ara eyi ti angbe kiri bayo yio di erupe, sibe Emimoti ongbeninu wa ni ireti ajinde wa.

Romu 8:1-8

Ase tiese ni lori ara atijo ni ofin lori ese ati iku

Romu 7:7-25

Nje ofin je ese ni?

Romu 7:1-6

Atunyewo ninu ofin Mose nipa igbeyawo

Romu 6:13-23

Ijo Olorun lo ye ko je amona ti o toka si igbe aye mimo