2 Samuelii 4-5
-
2Samueli 4
Close
2 Samuelii 2-3
Dafidi se ohun ologbon o mu awon ti o sin Oba Saulu mo ra.
1 Samueli 31:1-11
Saulu ko fe ku si owo ota re ofara mo lati pa ara re.
1 Samueli 29-30
Opo igba ni awa omo olorun ko mo pe Olorun nse alabo lori wa ki ama ba segbe si owo ota ti on se bi ore fun wa.
1 Samueli 27-28
Ko to ki enikeni se idajo eni ami ororo Olorun, olorun ni oludajo gbogbo wa.
1 Samueli 25:26-26:25
Olorun a ma gbagbe ese wa, ti o ba ti darijiwa
1 Samueli 24:1-25:25
Jonatani je ore oni moran rere si Dafidi
1 Samueli 22-23
Bio tile jewipe Dafidi ni awon jagunjagun ko fi ti awon alufa kefre.
1 Samueli 20:3-21:15
Jonatani je ore tooto, ore otito ni oye ki a je fun ara wa.
1 Samueli 18:1-20:3
Dafidi yan okuta marun lati koju Golayati ati awon omo re merin.
1 Samueli 16-17
Olorun n wow a lati inu wa, arinu rode nii se.