Romu 14:17-15:3

Ohun kohun ti kii se ti igbagbo, ese ni

Romu 14:5-17

Mase je ki enikeni ki o daolejo niti eran jije

Romu 14:1-5

Gbogbo oni gbagbo lo ni lati ni idaniloju igbala re

Romu 13

Ani lati fi ara ji fun ase awon ijoba nitoriwipe Olorun mo nipa ibosipo won

Romu 12:12-13:1

Ti o ba seese ki awa ni Alafia pelu gbogbo alaigbagbo

Romu 12:2-11

Ipe fun wa lati fi ara wa fun Olorun ni ebo aye mimo

Romu 11:26-12:2

Niwon igbati ti Olorun lee gba awon kenferi to sun mo, O lee gba omo Isreali to ba ronu pada

Romu 11:11-25

Saved by grace

Romu 10:7-11:10

Kristi ni opin gbogbo ofin

Romu 9:25-10:10

Ipo Isreali ni wipe won sonu, eyi si ni ipo won loni

Romu 9:4-24

Aposteli Paulu se alaye kikun lori awon ti ayan ati awon ti akoyan