Romu 15:25-16:2

Etan po ninu aye kritiani ni lati sora fun awon ti on ja fun inu nipase etan.

Romu 15:17-26

Inu Olorun ko dun si eri ti o toka si igberaga

Romu 15:4-16

Ibukun Olorun ti owa ninu Bibeli, ki se oun asiri fun awon kenferi.

Romu 14:17-15:3

Ohun kohun ti kii se ti igbagbo, ese ni

Romu 14:5-17

Mase je ki enikeni ki o daolejo niti eran jije

Romu 14:1-5

Gbogbo oni gbagbo lo ni lati ni idaniloju igbala re

Romu 13

Ani lati fi ara ji fun ase awon ijoba nitoriwipe Olorun mo nipa ibosipo won

Romu 12:12-13:1

Ti o ba seese ki awa ni Alafia pelu gbogbo alaigbagbo

Romu 12:2-11

Ipe fun wa lati fi ara wa fun Olorun ni ebo aye mimo

Romu 11:26-12:2

Niwon igbati ti Olorun lee gba awon kenferi to sun mo, O lee gba omo Isreali to ba ronu pada

Romu 11:11-25

Saved by grace