Hide
View
Da Appko
Ni ore ofe lori App store
Ijo Olorun lo ye ko je amona ti o toka si igbe aye mimo
Idalare so eniyan di eni rere, iwenumo so eniyan di enimimo
Ninu igbala Olorun ni ati sowa di eni rere
Gbogbo omo lehin Kristi lo ni ase si Olorun nipa adura
Dafidi gbe labe ofin sugbon Abrahamu ko gbe labe ofin.
Igbe aye mimo ko se gba ninu ofin.
Bi awon juu se ni aye beni aye naa lo pelu ise.
Paulu se afiwe igbala ati ese.
Majemu lailai fi Olorun ibinu han, sugbon majemu titun fi Olorun ife han
O ye ki awa naa setan lati di gbese nitori ihinrere fun gbogbo eniyan
Hiramu jeri wipe ologbon eniyan ni Solomoni iise
Ikopa ninu ohun ti aba ko ma n mu ki eniyan lee se dada.
Ese Dafidi di pupo, o dki apa niyan.
Ese Dafidi nipa kika awon eniyan.
Batseba je iyawo ti Dafidi fe nipase agbere sibe o ri aanu gba
Fowosi email
Sign up for the TWR360 Newsletter
Access updates, news, Biblical teaching and inspirational messages from powerful Christian voices.
E se fun iforukosile lati gba awon iwe irohin lati owo TWR360