Jobu 3:14-26
-
Jobu 3:14-26
Close
Olorun ti mo odi aabo yi gbogbo eniyan ka, onigbagbo tabi alai gbagbo.
Jobu 2:4-3:13
Ni ojo kan emi ati iwo na yio wa si iwaju Olorun lati jabo ise wa fun, nitori ohun ni eleda wa.
Jobu 1:6-2:3
ile aye yi je ibi joko Satani, ko ti'n lo si orun apaadi.
Jobu 1:1-5
ile Usi je ile ti Jobu ngbe
Esteri 9-10
Nigbati ireti ba pin Olorun a dide iranlowo
Esteri 8
asiko ti Olorun ba fe eniyan tiko ba se, yio ri ifarahan ogo re
Esteri 6:7-7:10
eni ti yio se aanu fun kole sa lai se
Esteri 5:5-6:8
Asilo ore ofe lon se akoba fu julo ni awujo wa loni.
Esteri 4:3-5:4
Akoko ti a da wa fun lati se ohun rere ni akoko ise ti Olorun da wa fun.
Esteri 3:7-4:2
Hamani ni o mu to Oba wipe awon ajoji ngbe pelu won ni ile naa
Esteri 2:13-3:6
ko si oun ija ti a ko si awon omo ju ti yio se rere